2 Sámúẹ́lì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí àwọn ará Síríà tó wà ní Damásíkù+ wá ran Hadadésà ọba Sóbà lọ́wọ́, Dáfídì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) lára àwọn ará Síríà+ náà.
5 Nígbà tí àwọn ará Síríà tó wà ní Damásíkù+ wá ran Hadadésà ọba Sóbà lọ́wọ́, Dáfídì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) lára àwọn ará Síríà+ náà.