-
Jẹ́nẹ́sísì 36:40-43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 Orúkọ àwọn séríkí tó jẹ́ ọmọ Ísọ̀ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, ibi tí wọ́n ń gbé àti orúkọ wọn: Séríkí Tímínà, Séríkí Álíífà, Séríkí Jététì,+ 41 Séríkí Oholibámà, Séríkí Élà, Séríkí Pínónì, 42 Séríkí Kénásì, Séríkí Témánì, Séríkí Míbúsárì, 43 Séríkí Mágídíélì àti Séríkí Írámù. Àwọn ni séríkí Édómù gẹ́gẹ́ bí ibi tí wọ́n ń gbé ní ilẹ̀ tó jẹ́ ohun ìní+ wọn. Èyí ni Ísọ̀, bàbá Édómù.+
-