2 Sámúẹ́lì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jóábù wá fún ọba ní iye àwọn èèyàn tó forúkọ wọn sílẹ̀. Ogójì ọ̀kẹ́ (800,000) jagunjagun tó ní idà ló wà ní Ísírẹ́lì, àwọn ọkùnrin Júdà sì jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (500,000).+
9 Jóábù wá fún ọba ní iye àwọn èèyàn tó forúkọ wọn sílẹ̀. Ogójì ọ̀kẹ́ (800,000) jagunjagun tó ní idà ló wà ní Ísírẹ́lì, àwọn ọkùnrin Júdà sì jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (500,000).+