Hágáì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ‘Ta ló ṣẹ́ kù nínú yín tó rí ilé* yìí nígbà tó ṣì rẹwà?+ Báwo ló ṣe rí lójú yín báyìí? Tí ẹ bá fi wé ti tẹ́lẹ̀, ǹjẹ́ ó ṣì já mọ́ nǹkan kan?’+
3 ‘Ta ló ṣẹ́ kù nínú yín tó rí ilé* yìí nígbà tó ṣì rẹwà?+ Báwo ló ṣe rí lójú yín báyìí? Tí ẹ bá fi wé ti tẹ́lẹ̀, ǹjẹ́ ó ṣì já mọ́ nǹkan kan?’+