Sáàmù 68:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Nítorí tẹ́ńpìlì rẹ tó wà ní Jerúsálẹ́mù,+Àwọn ọba yóò mú àwọn ẹ̀bùn wá fún ọ.+