Ẹ́kísódù 2:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà, Mósè gbà láti dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin náà, ó sì fún Mósè ní Sípórà+ ọmọ rẹ̀ kó fi ṣe aya. 22 Nígbà tó yá, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, Mósè sì sọ ọ́ ní Gẹ́ṣómù,*+ torí ó sọ pé, “Mo ti di àjèjì nílẹ̀ àjèjì.”+
21 Lẹ́yìn náà, Mósè gbà láti dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin náà, ó sì fún Mósè ní Sípórà+ ọmọ rẹ̀ kó fi ṣe aya. 22 Nígbà tó yá, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, Mósè sì sọ ọ́ ní Gẹ́ṣómù,*+ torí ó sọ pé, “Mo ti di àjèjì nílẹ̀ àjèjì.”+