Ẹ́kísódù 18:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjèèjì.+ Ọ̀kan ń jẹ́ Gẹ́ṣómù,*+ torí Mósè sọ pé, “mo ti di àjèjì nílẹ̀ òkèèrè.” 4 Èkejì ń jẹ́ Élíésérì,* torí ó sọ pé, “Ọlọ́run bàbá mi ni olùrànlọ́wọ́ mi, ẹni tó gbà mí lọ́wọ́ idà Fáráò.”+
3 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ méjèèjì.+ Ọ̀kan ń jẹ́ Gẹ́ṣómù,*+ torí Mósè sọ pé, “mo ti di àjèjì nílẹ̀ òkèèrè.” 4 Èkejì ń jẹ́ Élíésérì,* torí ó sọ pé, “Ọlọ́run bàbá mi ni olùrànlọ́wọ́ mi, ẹni tó gbà mí lọ́wọ́ idà Fáráò.”+