Jẹ́nẹ́sísì 30:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, Sílípà ìránṣẹ́ Líà bí ọmọkùnrin kejì fún Jékọ́bù. 13 Líà sì sọ pé: “Ayọ̀ mi kún! Ó dájú pé àwọn ọmọbìnrin máa pè mí ní aláyọ̀.”+ Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Áṣérì.*+ Jẹ́nẹ́sísì 49:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Oúnjẹ* Áṣérì+ yóò pọ̀ gan-an,* yóò sì pèsè oúnjẹ tó tọ́ sí ọba.+
12 Lẹ́yìn náà, Sílípà ìránṣẹ́ Líà bí ọmọkùnrin kejì fún Jékọ́bù. 13 Líà sì sọ pé: “Ayọ̀ mi kún! Ó dájú pé àwọn ọmọbìnrin máa pè mí ní aláyọ̀.”+ Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Áṣérì.*+