1 Kíróníkà 26:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nínú àwọn ọmọ Hébúrónì, Jéríjà+ ni olórí àwọn ọmọ Hébúrónì bí ìran wọn ṣe tẹ̀ léra nínú agbo ilé bàbá wọn. Ní ogójì ọdún ìjọba Dáfídì,+ wọ́n wá àwọn akíkanjú àti ọ̀jáfáfá ọkùnrin, wọ́n sì rí láàárín àwọn ọmọ Hébúrónì ní Jásérì+ ní Gílíádì.
31 Nínú àwọn ọmọ Hébúrónì, Jéríjà+ ni olórí àwọn ọmọ Hébúrónì bí ìran wọn ṣe tẹ̀ léra nínú agbo ilé bàbá wọn. Ní ogójì ọdún ìjọba Dáfídì,+ wọ́n wá àwọn akíkanjú àti ọ̀jáfáfá ọkùnrin, wọ́n sì rí láàárín àwọn ọmọ Hébúrónì ní Jásérì+ ní Gílíádì.