1 Kíróníkà 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Dáfídì wá sọ fún àwọn olórí ọmọ Léfì pé kí wọ́n yan àwọn arákùnrin wọn tó jẹ́ akọrin láti máa fi ayọ̀ kọrin, kí wọ́n máa lo àwọn ohun ìkọrin, ìyẹn àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ pẹ̀lú síńbálì.*+ 1 Kíróníkà 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Hémánì,+ Ásáfù+ àti Étánì tí wọ́n jẹ́ akọrin ni wọ́n á máa fi síńbálì bàbà+ kọrin;
16 Dáfídì wá sọ fún àwọn olórí ọmọ Léfì pé kí wọ́n yan àwọn arákùnrin wọn tó jẹ́ akọrin láti máa fi ayọ̀ kọrin, kí wọ́n máa lo àwọn ohun ìkọrin, ìyẹn àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ pẹ̀lú síńbálì.*+