-
1 Kíróníkà 26:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nígbà náà, kèké tí wọ́n ṣẹ́ fún ẹnubodè ìlà oòrùn jáde fún Ṣelemáyà. Wọ́n ṣẹ́ kèké náà fún Sekaráyà ọmọ rẹ̀, agbani-nímọ̀ràn tó lóye, kèké rẹ̀ sì mú àríwá.
-
-
1 Kíróníkà 26:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Bí wọ́n ṣe pín àwọn aṣọ́bodè náà nìyẹn látinú àwọn ọmọ Kórà àti àwọn ọmọ Mérárì.
-