1 Sámúẹ́lì 27:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ákíṣì á béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ibo ni ẹ ti lọ kó nǹkan lónìí?” Dáfídì á dáhùn pé: “Apá gúúsù* Júdà”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn ọmọ Jéráméélì”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn Kénì”+ ni.
10 Ákíṣì á béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Ibo ni ẹ ti lọ kó nǹkan lónìí?” Dáfídì á dáhùn pé: “Apá gúúsù* Júdà”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn ọmọ Jéráméélì”+ tàbí “Apá gúúsù àwọn Kénì”+ ni.