1 Kíróníkà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, Dáfídì sọ pé: “Ẹni tó bá kọ́kọ́ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì ló máa di balógun* àti ìjòyè.” Jóábù+ ọmọ Seruáyà ló kọ́kọ́ lọ, ó sì di balógun.
6 Torí náà, Dáfídì sọ pé: “Ẹni tó bá kọ́kọ́ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì ló máa di balógun* àti ìjòyè.” Jóábù+ ọmọ Seruáyà ló kọ́kọ́ lọ, ó sì di balógun.