1 Kíróníkà 27:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ásímáfẹ́tì ọmọ Ádíélì ló ń bójú tó àwọn ibi ìṣúra ọba.+ Jónátánì ọmọ Ùsáyà ló ń bójú tó àwọn ilé ìkẹ́rùsí* ní pápá, ní àwọn ìlú, ní àwọn abúlé àti ní àwọn ilé gogoro. 1 Kíróníkà 27:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ṣítíráì ará Ṣárónì ló ń bójú tó àwọn ọ̀wọ́ ẹran tó ń jẹko ní Ṣárónì,+ Ṣáfátì ọmọ Ádíláì ló sì ń bójú tó àwọn ọ̀wọ́ ẹran tó wà ní àwọn àfonífojì.*
25 Ásímáfẹ́tì ọmọ Ádíélì ló ń bójú tó àwọn ibi ìṣúra ọba.+ Jónátánì ọmọ Ùsáyà ló ń bójú tó àwọn ilé ìkẹ́rùsí* ní pápá, ní àwọn ìlú, ní àwọn abúlé àti ní àwọn ilé gogoro.
29 Ṣítíráì ará Ṣárónì ló ń bójú tó àwọn ọ̀wọ́ ẹran tó ń jẹko ní Ṣárónì,+ Ṣáfátì ọmọ Ádíláì ló sì ń bójú tó àwọn ọ̀wọ́ ẹran tó wà ní àwọn àfonífojì.*