Diutarónómì 31:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá dé bá wọn,+ orin yìí máa jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wọn, (torí àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò gbọ́dọ̀ gbàgbé rẹ̀), torí mo ti mọ ohun tí wọ́n ń rò lọ́kàn+ kí n tiẹ̀ tó mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀.” Sáàmù 139:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 O mọ ìgbà tí mo bá jókòó àti ìgbà tí mo bá dìde.+ Láti ibi tó jìnnà réré, o mọ ohun tí mò ń rò.+
21 Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá dé bá wọn,+ orin yìí máa jẹ́ ẹlẹ́rìí fún wọn, (torí àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò gbọ́dọ̀ gbàgbé rẹ̀), torí mo ti mọ ohun tí wọ́n ń rò lọ́kàn+ kí n tiẹ̀ tó mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀.”