Sáàmù 76:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n ti kó ẹrù àwọn tó nígboyà. Oorun ti gbé wọn lọ;+Gbogbo àwọn jagunjagun ò lè ṣe nǹkan kan.+