-
1 Àwọn Ọba 1:45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Lẹ́yìn náà, àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì fòróró yàn án ṣe ọba ní Gíhónì. Wọ́n wá kúrò níbẹ̀, inú wọn ń dùn, ariwo sì gba ìlú kan. Ariwo tí ẹ gbọ́ nìyẹn.
-