-
2 Àwọn Ọba 20:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ní àkókò yẹn, ọba Bábílónì, ìyẹn Berodaki-báládánì ọmọ Báládánì fi àwọn lẹ́tà àti ẹ̀bùn ránṣẹ́ sí Hẹsikáyà, torí ó gbọ́ pé Hẹsikáyà ṣàìsàn.+
-