Léfítíkù 19:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tòun ti ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.+ “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ woṣẹ́, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pidán.+