ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 22:3-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jòsáyà, ọba rán Ṣáfánì akọ̀wé tó jẹ́ ọmọ Asaláyà ọmọ Méṣúlámù sí ilé Jèhófà,+ ó ní: 4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+ 5 Ní kí wọ́n kó o fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà, àwọn yìí ló máa fún àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà láti tún àwọn ibi tó bà jẹ́* lára ilé náà ṣe,+ 6 ìyẹn àwọn oníṣẹ́ ọnà àti àwọn kọ́lékọ́lé àti àwọn mọlémọlé; owó yìí ni kí wọ́n fi ra àwọn ẹ̀là gẹdú àti àwọn òkúta gbígbẹ́ tí wọ́n á fi tún ilé náà ṣe.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́