Ẹ́sírà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní báyìí, jẹ́ ká bá Ọlọ́run wa dá májẹ̀mú+ pé a máa lé gbogbo àwọn aya náà lọ àti àwọn ọmọ tí wọ́n bí, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa àti ohun tí àwọn tó ní ọ̀wọ̀* fún àṣẹ Ọlọ́run wa sọ.+ Ká ṣe ohun tí Òfin sọ.
3 Ní báyìí, jẹ́ ká bá Ọlọ́run wa dá májẹ̀mú+ pé a máa lé gbogbo àwọn aya náà lọ àti àwọn ọmọ tí wọ́n bí, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa àti ohun tí àwọn tó ní ọ̀wọ̀* fún àṣẹ Ọlọ́run wa sọ.+ Ká ṣe ohun tí Òfin sọ.