Léfítíkù 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní+ ni kí ẹ ṣe Ìrékọjá+ fún Jèhófà. Diutarónómì 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Máa rántí oṣù Ábíbù,* kí o sì máa ṣe ayẹyẹ Ìrékọjá fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ torí pé oṣù Ábíbù ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ kúrò ní Íjíbítì ní òru.+
16 “Máa rántí oṣù Ábíbù,* kí o sì máa ṣe ayẹyẹ Ìrékọjá fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ torí pé oṣù Ábíbù ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ kúrò ní Íjíbítì ní òru.+