1 Kíróníkà 16:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fi Ásáfù+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀ níwájú àpótí májẹ̀mú Jèhófà kí wọ́n lè máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí+ nígbà gbogbo, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ojoojúmọ́.+
37 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fi Ásáfù+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀ níwájú àpótí májẹ̀mú Jèhófà kí wọ́n lè máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí+ nígbà gbogbo, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ojoojúmọ́.+