2 Àwọn Ọba 23:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Nígbà ayé rẹ̀, Fáráò Nẹ́kò ọba Íjíbítì wá bá ọba Ásíríà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, Ọba Jòsáyà sì jáde lọ kò ó lójú; àmọ́ nígbà tí Nẹ́kò rí i, ó pa á ní Mẹ́gídò.+
29 Nígbà ayé rẹ̀, Fáráò Nẹ́kò ọba Íjíbítì wá bá ọba Ásíríà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, Ọba Jòsáyà sì jáde lọ kò ó lójú; àmọ́ nígbà tí Nẹ́kò rí i, ó pa á ní Mẹ́gídò.+