2 Àwọn Ọba 24:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọba Bábílónì fi Matanáyà àbúrò bàbá Jèhóákínì+ jọba ní ipò rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Sedekáyà.+
17 Ọba Bábílónì fi Matanáyà àbúrò bàbá Jèhóákínì+ jọba ní ipò rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Sedekáyà.+