2 Àwọn Ọba 24:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lẹ́yìn náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í rán àwọn akónilẹ́rù* àwọn ará Kálídíà,+ ti àwọn ará Síríà, ti àwọn ọmọ Móábù àti ti àwọn ọmọ Ámónì sí i. Ó ń rán wọn sí Júdà léraléra láti pa á run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà+ gbẹnu àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, wòlíì sọ.
2 Lẹ́yìn náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í rán àwọn akónilẹ́rù* àwọn ará Kálídíà,+ ti àwọn ará Síríà, ti àwọn ọmọ Móábù àti ti àwọn ọmọ Ámónì sí i. Ó ń rán wọn sí Júdà léraléra láti pa á run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà+ gbẹnu àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, wòlíì sọ.