Dáníẹ́lì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní tìrẹ, ọba, Ọlọ́run Gíga Jù Lọ gbé ìjọba fún Nebukadinésárì bàbá rẹ, ó sọ ọ́ di ẹni ńlá, ó sì fún un ní ògo àti ọlá ńlá.+
18 Ní tìrẹ, ọba, Ọlọ́run Gíga Jù Lọ gbé ìjọba fún Nebukadinésárì bàbá rẹ, ó sọ ọ́ di ẹni ńlá, ó sì fún un ní ògo àti ọlá ńlá.+