Ẹ́kísódù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+ Ẹ́kísódù 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn náà, ó mú ìwé májẹ̀mú, ó kà á sókè fún àwọn èèyàn náà.+ Wọ́n sì sọ pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe, a ó sì máa ṣègbọràn.”+
5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+
7 Lẹ́yìn náà, ó mú ìwé májẹ̀mú, ó kà á sókè fún àwọn èèyàn náà.+ Wọ́n sì sọ pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe, a ó sì máa ṣègbọràn.”+