Sáàmù 132:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+
12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+