Ẹ́sírà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì + pẹ̀lú àwọn tó wà nígbèkùn tẹ́lẹ̀ fi ìdùnnú ṣe ayẹyẹ ṣíṣí* ilé Ọlọ́run yìí.
16 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì + pẹ̀lú àwọn tó wà nígbèkùn tẹ́lẹ̀ fi ìdùnnú ṣe ayẹyẹ ṣíṣí* ilé Ọlọ́run yìí.