42 A máa gbé ọbabìnrin gúúsù dìde láti ṣèdájọ́ ìran yìí, ó sì máa dá a lẹ́bi, torí ó wá láti ìkángun ayé kó lè gbọ́ ọ̀rọ̀ ọgbọ́n Sólómọ́nì.+ Àmọ́ ẹ wò ó! ohun kan tó ju Sólómọ́nì lọ wà níbí.+
31 A máa gbé ọbabìnrin gúúsù+ dìde láti ṣèdájọ́ àwọn èèyàn ìran yìí, ó sì máa dá wọn lẹ́bi, torí ó wá láti ìkángun ayé kó lè gbọ́ ọ̀rọ̀ ọgbọ́n Sólómọ́nì. Àmọ́ ẹ wò ó! ohun kan tó ju Sólómọ́nì lọ wà níbí.+