1 Àwọn Ọba 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹnu ọ̀nà tó wọ yàrá ẹ̀gbẹ́ tó wà ní ìsàlẹ̀ wà lápá gúúsù* ilé náà,+ àtẹ̀gùn tó yí po ni wọ́n ń gbà gòkè lọ sí yàrá àárín àti láti yàrá àárín dé yàrá kẹta tó wà lókè.
8 Ẹnu ọ̀nà tó wọ yàrá ẹ̀gbẹ́ tó wà ní ìsàlẹ̀ wà lápá gúúsù* ilé náà,+ àtẹ̀gùn tó yí po ni wọ́n ń gbà gòkè lọ sí yàrá àárín àti láti yàrá àárín dé yàrá kẹta tó wà lókè.