Jẹ́nẹ́sísì 49:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọmọ kìnnìún+ ni Júdà. Ọmọ mi, ìwọ yóò jẹ ẹran tí o pa, wàá sì dìde kúrò níbẹ̀. Ó ti dùbúlẹ̀, ó sì nà tàntàn bíi kìnnìún. Ó rí bíi kìnnìún, ta ló láyà láti jí i?
9 Ọmọ kìnnìún+ ni Júdà. Ọmọ mi, ìwọ yóò jẹ ẹran tí o pa, wàá sì dìde kúrò níbẹ̀. Ó ti dùbúlẹ̀, ó sì nà tàntàn bíi kìnnìún. Ó rí bíi kìnnìún, ta ló láyà láti jí i?