1 Àwọn Ọba 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọba tún fi eyín erin ṣe ìtẹ́ ńlá kan,+ ó sì fi wúrà tí a yọ́ mọ́ bò ó.+