ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 5:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ní báyìí, sọ fún àwọn èèyàn rẹ pé kí wọ́n gé igi kédárì ti Lẹ́bánónì+ fún mi. Àwọn ìránṣẹ́ mi á bá àwọn ìránṣẹ́ rẹ ṣiṣẹ́, màá san owó iṣẹ́ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ, iye tí o bá sì sọ ni màá san, nítorí o mọ̀ pé kò sí ìkankan lára wa tó mọ bí a ṣe ń gé igi bí àwọn ọmọ Sídónì.”+

  • 1 Àwọn Ọba 5:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Torí náà, Hírámù ránṣẹ́ sí Sólómọ́nì pé: “Mo ti gbọ́ iṣẹ́ tí o rán sí mi. Màá ṣe gbogbo ohun tí o fẹ́, màá fún ọ ní gẹdú igi kédárì àti igi júnípà.+

  • 2 Kíróníkà 3:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ó fi igi júnípà bo ilé ńlá náà, lẹ́yìn náà, ó fi wúrà tó dára bò ó,+ ó wá ya àwòrán igi ọ̀pẹ+ àti ẹ̀wọ̀n+ sára rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́