-
2 Kíróníkà 11:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lẹ́yìn rẹ̀, ó fẹ́ Máákà ọmọ ọmọ Ábúsálómù.+ Nígbà tó yá, ó bí Ábíjà,+ Átáì, Sísà àti Ṣẹ́lómítì fún un. 21 Rèhóbóámù nífẹ̀ẹ́ Máákà ọmọ ọmọ Ábúsálómù ju gbogbo àwọn ìyàwó rẹ̀ yòókù àti àwọn wáhàrì*+ rẹ̀ lọ. Ó ní ìyàwó méjìdínlógún (18) àti ọgọ́ta (60) wáhàrì, ó sì bí ọmọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n (28) àti ọgọ́ta (60) ọmọbìnrin.
-