Jẹ́nẹ́sísì 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+ 2 Sámúẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+ Sáàmù 78:70, 71 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 70 Ó yan Dáfídì+ ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì mú un kúrò nínú ọgbà àgùntàn,+71 Kúrò ní ibi tó ti ń tọ́jú àwọn abo àgùntàn tó ń fọ́mọ lọ́mú;Ó fi í ṣe olùṣọ́ àgùntàn lórí Jékọ́bù, àwọn èèyàn rẹ̀+Àti lórí Ísírẹ́lì, ogún rẹ̀.+
10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+
8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+
70 Ó yan Dáfídì+ ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì mú un kúrò nínú ọgbà àgùntàn,+71 Kúrò ní ibi tó ti ń tọ́jú àwọn abo àgùntàn tó ń fọ́mọ lọ́mú;Ó fi í ṣe olùṣọ́ àgùntàn lórí Jékọ́bù, àwọn èèyàn rẹ̀+Àti lórí Ísírẹ́lì, ogún rẹ̀.+