Diutarónómì 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kò sì gbọ́dọ̀ kó ìyàwó rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀, kí ọkàn rẹ̀ má bàa yí pa dà;+ bẹ́ẹ̀ ni kò gbọ́dọ̀ kó fàdákà àti wúrà rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀.+
17 Kò sì gbọ́dọ̀ kó ìyàwó rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀, kí ọkàn rẹ̀ má bàa yí pa dà;+ bẹ́ẹ̀ ni kò gbọ́dọ̀ kó fàdákà àti wúrà rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀.+