ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 34:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni Jòsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+

  • 2 Kíróníkà 34:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Láfikún sí i, wọ́n wó pẹpẹ àwọn Báálì lulẹ̀ níṣojú rẹ̀, ó sì gé àwọn pẹpẹ tùràrí tó wà lókè orí wọn lulẹ̀. Ó tún fọ́ àwọn òpó òrìṣà* àti àwọn ère gbígbẹ́ pẹ̀lú àwọn ère onírin* sí wẹ́wẹ́, ó lọ̀ wọ́n lẹ́búlẹ́bú, ó sì wọ́n ekuru wọn sórí sàréè àwọn tó ń rúbọ sí wọn tẹ́lẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́