ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 11:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nígbà tí Rèhóbóámù dé Jerúsálẹ́mù, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ló pe ilé Júdà àti Bẹ́ńjámínì+ jọ, ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án (180,000) akọgun,* láti bá Ísírẹ́lì jà, kí wọ́n lè gba ìjọba pa dà fún Rèhóbóámù.+

  • 2 Kíróníkà 11:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 ó sì fún àwọn ìlú kọ̀ọ̀kan ní apata ńlá àti aṣóró; ó mú kí wọ́n lágbára gan-an. Ó sì ń ṣàkóso lórí Júdà àti Bẹ́ńjámínì nìṣó.

  • 2 Kíróníkà 13:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nítorí náà, Ábíjà kó ogún ọ̀kẹ́ (400,000) àwọn ọmọ ogun tí wọ́n lákíkanjú, tí wọ́n sì jẹ́ akọgun* lọ sójú ogun.+ Bákan náà, Jèróbóámù kó ogójì ọ̀kẹ́ (800,000) àwọn ọkùnrin tó mọṣẹ́ ogun,* àwọn jagunjagun tó lákíkanjú, ó sì tò wọ́n lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti dojú kọ ọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́