-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Kéílà, Ákísíbù àti Máréṣà, gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́sàn-án pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
2 Kíróníkà 11:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Rèhóbóámù ń gbé Jerúsálẹ́mù, ó sì kọ́ àwọn ìlú olódi sí Júdà.
-