1 Sámúẹ́lì 17:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+ Sáàmù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè. Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+
45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+
5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè.