-
Jóṣúà 7:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Tí àwọn ọmọ Kénáánì àti gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà bá gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n á yí wa ká, wọ́n á sì pa orúkọ wa rẹ́ kúrò ní ayé, kí lo máa wá ṣe nípa orúkọ ńlá rẹ?”+
-
-
Sáàmù 9:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Dìde, Jèhófà! Má ṣe jẹ́ kí ẹni kíkú borí.
Jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè gba ìdájọ́ níwájú rẹ.+
-