2 Kíróníkà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Bákan náà, ó fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú rírẹ̀dòdò àti aṣọ àtàtà ṣe aṣọ ìdábùú,+ ó sì ṣe iṣẹ́ ọnà kérúbù sí i lára.+
14 Bákan náà, ó fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú rírẹ̀dòdò àti aṣọ àtàtà ṣe aṣọ ìdábùú,+ ó sì ṣe iṣẹ́ ọnà kérúbù sí i lára.+