ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, nígbà tí Sábáàtì+ ti kọjá, Màríà Magidalénì, Màríà+ ìyá Jémíìsì àti Sàlómẹ̀ ra àwọn èròjà tó ń ta sánsán kí wọ́n lè wá fi pa á lára.+

  • Lúùkù 23:55, 56
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 55 Àmọ́ àwọn obìnrin tó bá a wá láti Gálílì tẹ̀ lé e lọ, wọ́n yọjú wo ibojì* náà, wọ́n sì rí i bí wọ́n ṣe tẹ́ òkú rẹ̀,+ 56 wọ́n wá pa dà lọ pèsè èròjà tó ń ta sánsán àti àwọn òróró onílọ́fínńdà. Àmọ́ wọ́n sinmi ní Sábáàtì+ bí a ṣe pa á láṣẹ.

  • Jòhánù 19:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Torí náà, wọ́n gbé òkú Jésù, wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀* dì í pẹ̀lú àwọn èròjà tó ń ta sánsán náà,+ bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́