2 Kíróníkà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhóṣáfátì ní ọrọ̀ àti ògo tó pọ̀ gan-an,+ àmọ́ ó bá Áhábù+ dána.