-
Nọ́ńbà 16:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Tó bá jẹ́ pé bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú làwọn èèyàn yìí máa kú, tó bá sì jẹ́ irú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí gbogbo aráyé ń jẹ làwọn náà máa jẹ, a jẹ́ pé Jèhófà kọ́ ló rán mi.+
-