2 Sámúẹ́lì 24:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Dáfídì mọ pẹpẹ+ kan síbẹ̀ fún Jèhófà, ó sì rú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀. Lẹ́yìn náà, Jèhófà gbọ́ ẹ̀bẹ̀ ilẹ̀ náà,+ àjàkálẹ̀ àrùn tó ń pa àwọn èèyàn Ísírẹ́lì sì dáwọ́ dúró. 1 Kíróníkà 21:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lẹ́yìn náà, áńgẹ́lì Jèhófà ní kí Gádì+ sọ fún Dáfídì pé kó lọ ṣé pẹpẹ kan fún Jèhófà ní ibi ìpakà Ọ́nánì ará Jébúsì.+
25 Dáfídì mọ pẹpẹ+ kan síbẹ̀ fún Jèhófà, ó sì rú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀. Lẹ́yìn náà, Jèhófà gbọ́ ẹ̀bẹ̀ ilẹ̀ náà,+ àjàkálẹ̀ àrùn tó ń pa àwọn èèyàn Ísírẹ́lì sì dáwọ́ dúró.
18 Lẹ́yìn náà, áńgẹ́lì Jèhófà ní kí Gádì+ sọ fún Dáfídì pé kó lọ ṣé pẹpẹ kan fún Jèhófà ní ibi ìpakà Ọ́nánì ará Jébúsì.+