1 Àwọn Ọba 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà Èlíjà wá bá gbogbo àwọn èèyàn náà, ó sì sọ pé: “Ìgbà wo lẹ máa ṣiyèméjì* dà?+ Tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́, ẹ tẹ̀ lé e;+ àmọ́ tó bá jẹ́ pé Báálì ni, ẹ tẹ̀ lé e!” Àwọn èèyàn náà kò sì fèsì kankan.
21 Lẹ́yìn náà Èlíjà wá bá gbogbo àwọn èèyàn náà, ó sì sọ pé: “Ìgbà wo lẹ máa ṣiyèméjì* dà?+ Tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́, ẹ tẹ̀ lé e;+ àmọ́ tó bá jẹ́ pé Báálì ni, ẹ tẹ̀ lé e!” Àwọn èèyàn náà kò sì fèsì kankan.