1 Àwọn Ọba 22:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Jèhóṣáfátì tún ṣe àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì* láti máa fi kó wúrà+ wá láti Ófírì, ṣùgbọ́n wọn ò lè lọ torí pé àwọn ọkọ̀ òkun náà fọ́ ní Esioni-gébérì.+
48 Jèhóṣáfátì tún ṣe àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì* láti máa fi kó wúrà+ wá láti Ófírì, ṣùgbọ́n wọn ò lè lọ torí pé àwọn ọkọ̀ òkun náà fọ́ ní Esioni-gébérì.+